Gẹn 1:27 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bẹ̃li Ọlọrun dá enia li aworan rẹ̀, li aworan Ọlọrun li o dá a; ati akọ ati abo li o dá wọn.

Gẹn 1

Gẹn 1:20-31