Gẹn 1:25 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ọlọrun si dá ẹranko ilẹ ni irú tirẹ̀, ati ẹran-ọ̀sin ni irú tirẹ̀, ati ohun gbogbo ti nrakò lori ilẹ ni irú tirẹ̀: Ọlọrun si ri pe o dara.

Gẹn 1

Gẹn 1:23-26