Gẹn 1:22 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ọlọrun si súre fun wọn pe, Ẹ ma bi si i, ẹ si mã rẹ̀, ki ẹ kún inu omi li okun, ki ẹiyẹ ki o si ma rẹ̀ ni ilẹ.

Gẹn 1

Gẹn 1:12-29