Gẹn 1:20 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ọlọrun si wipe, Ki omi ki o kún fun ọ̀pọlọpọ ẹdá alãye ti nrakò, ati ki ẹiyẹ ki o ma fò loke ilẹ li oju-ofurufu ọrun.

Gẹn 1

Gẹn 1:16-24