Gẹn 1:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ọlọrun si dá imọlẹ nla meji; imọlẹ ti o tobi lati ṣe akoso ọsán, ati imọlẹ ti o kere lati ṣe akoso oru: o si dá awọn irawọ pẹlu.

Gẹn 1

Gẹn 1:7-20