Gal 5:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori ninu Kristi Jesu ikọla kò jẹ ohun kan, tabi aikọla; ṣugbọn igbagbọ́ ti nṣiṣẹ nipa ifẹ.

Gal 5

Gal 5:4-14