Gal 5:15 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn bi ẹnyin ba mbù ara nyin ṣán, ti ẹ si njẹ ara nyin run, ẹ kiyesara ki ẹ máṣe pa ara nyin run.

Gal 5

Gal 5:14-20