Gal 4:22 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori a ti kọ ọ pe, Abrahamu ni ọmọ ọkunrin meji, ọkan lati ọdọ ẹrú-binrin, ati ọkan lati ọdọ omnira-obinrin.

Gal 4

Gal 4:17-31