Gal 2:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn Ju ti o kù si jùmọ ṣe agabagebe bẹ̃ gẹgẹ pẹlu rẹ̀; tobẹ̃ ti nwọn si fi agabagebe wọn fà Barnaba tikararẹ lọ.

Gal 2

Gal 2:11-17