Gal 1:20-22 Yorùbá Bibeli (YCE)

20. Nkan ti emi nkọ̀we si nyin yi, kiyesi i, niwaju Ọlọrun emi kò ṣeke.

21. Lẹhin na mo si wá si ẹkùn Siria ati ti Kilikia;

22. Mo sì jẹ ẹniti a kò mọ̀ li oju fun awọn ijọ ti o wà ninu Kristi ni Judea:

Gal 1