Gal 1:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

Lati fi Ọmọ rẹ̀ hàn ninu mi, ki emi le mã wasu rẹ̀ larin awọn Keferi; lojukanna emi kò bá ara ati ẹ̀jẹ gbìmọ pọ̀:

Gal 1

Gal 1:10-24