Filp 4:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹ máṣe aniyàn ohunkohun; ṣugbọn ninu ohun gbogbo, nipa adura ati ẹbẹ pẹlu idupẹ, ẹ mã fi ìbere nyin hàn fun Ọlọrun.

Filp 4

Filp 4:2-7