Filp 4:21-23 Yorùbá Bibeli (YCE)

21. Ẹ kí olukuluku enia mimọ́ ninu Kristi Jesu. Awọn ara ti o wà pẹlu mi kí nyin.

22. Gbogbo awọn enia mimọ́ kí nyin, papa awọn ti iṣe ti agbo ile Kesari.

23. Ore-ọfẹ Jesu Kristi Oluwa wa, ki o wà pẹlu ẹmi nyin. Amin.A kọ ọ si awọn ara Filippi lati Romu lọ lati ọwọ́ Epafroditu.

Filp 4