Filp 4:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

NITORINA, ẹnyin ará mi olufẹ, ti mo si nṣafẹri gidigidi, ayọ̀ ati ade mi, ẹ duro ṣinṣin bẹ̃ ninu Oluwa, ẹnyin olufẹ mi.

Filp 4

Filp 4:1-5