Est 9:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori Mordekai tobi ni ile ọba, okiki rẹ̀ si kàn ja gbogbo ìgberiko: nitori ọkunrin yi Mordekai ntobi siwaju ati siwaju.

Est 9

Est 9:1-10