Est 6:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ọba si wi pe, Tani mbẹ ni àgbala? Hamani si ti de àgbala akọkàn ile ọba, lati ba ọba sọ ọ lati so Mordekai rọ̀ sori igi giga ti o ti rì fun u.

Est 6

Est 6:1-14