Est 1:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati o fi ọrọ̀ ijọba rẹ̀ ti o logo, ati ọṣọ iyebiye ọlanla rẹ̀ han lọjọ pipọ̀, ani li ọgọsan ọjọ.

Est 1

Est 1:1-5