Esr 8:30 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bẹ̃ni awọn alufa ati awọn ọmọ Lefi mu fàdaka ati wura ti a wọ̀n pẹlu ohun-èlo wọnni lati ko wọn wá si Jerusalemu, sinu ile Ọlọrun wa.

Esr 8

Esr 8:26-36