Esr 6:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn ọmọ Israeli, awọn alufa, ati awọn ọmọ Lefi pẹlu awọn ọmọ ìgbekun ìyoku ṣe ìyasimimọ́ ile Ọlọrun yi pẹlu ayọ̀.

Esr 6

Esr 6:11-22