Esr 3:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

Lati ọjọ ikini oṣu keje ni nwọn bẹ̀rẹ lati ma rú ẹbọ sisun si Oluwa. Ṣugbọn a kò ti ifi ipilẹ tempili Oluwa lelẹ.

Esr 3

Esr 3:1-13