Esr 2:63 Yorùbá Bibeli (YCE)

Balẹ si wi fun wọn pe, ki nwọn ki o má jẹ ninu ohun mimọ́ julọ, titi alufa kan yio fi dide pẹlu Urimu ati pẹlu Tummimu.

Esr 2

Esr 2:59-70