Esr 2:55-57 Yorùbá Bibeli (YCE)

55. Awọn ọmọ awọn iranṣẹ Solomoni: awọn ọmọ Sotai, awọn ọmọ Sofereti, awọn ọmọ Peruda,

56. Awọn ọmọ Jaala, awọn ọmọ Darkoni, awọn ọmọ Giddeli,

57. Awọn ọmọ Ṣefatiah, awọn ọmọ Hattili, awọn ọmọ Pokereti ti Sebaimu, awọn ọmọ Ami.

Esr 2