Esr 2:33-37 Yorùbá Bibeli (YCE)

33. Awọn ọmọ Lodi, Hadidi ati Ono, ọrindilẹgbẹrin o le marun,

34. Awọn ọmọ Jeriko, ọtadinirinwo o le marun.

35. Awọn ọmọ Sanaa, egbejidilogun o le ọgbọn.

36. Awọn alufa; awọn ọmọ Jedaiah, ti idile Jeṣua, ogúndilẹgbẹrun o din meje.

37. Awọn ọmọ Immeri, ãdọtalelẹgbẹrun o le meji.

Esr 2