Esr 2:26-35 Yorùbá Bibeli (YCE)

26. Awọn ọmọ Rama ati Gaba, ẹgbẹta o le mọkanlelogun.

27. Awọn ọmọ Mikmasi, mejilelọgọfa.

28. Awọn enia Beteli ati Ai, igba o le mẹtalelogun.

29. Awọn ọmọ Nebo, mejilelãdọta.

30. Awọn ọmọ Magbiṣi mẹrindilọgọjọ.

31. Awọn ọmọ Elamu ekeji, ãdọtalelẹgbẹfa o le mẹrin.

32. Awọn ọmọ Harimu, ọrindinirinwo.

33. Awọn ọmọ Lodi, Hadidi ati Ono, ọrindilẹgbẹrin o le marun,

34. Awọn ọmọ Jeriko, ọtadinirinwo o le marun.

35. Awọn ọmọ Sanaa, egbejidilogun o le ọgbọn.

Esr 2