Esr 2:22-25 Yorùbá Bibeli (YCE) Awọn enia Netofa, mẹrindilọgọta. Awọn enia Anatotu, mejidilãdọje. Awọn ọmọ Asmafeti, mejilelogoji.