Esr 2:17-20 Yorùbá Bibeli (YCE)

17. Awọn ọmọ Besai, ọrindinirinwo o le mẹta.

18. Awọn ọmọ Jora, mejilelãdọfa.

19. Awọn ọmọ Haṣumu igba o le mẹtalelogun.

20. Awọn ọmọ Gibbari, marundilọgọrun.

Esr 2