Esr 10:41-44 Yorùbá Bibeli (YCE)

41. Asareeli, ati Ṣelemiah, Ṣemariah.

42. Ṣallumu, Amariah, ati Josefu.

43. Ninu awọn ọmọ Nebo; Jeieli, Mattitiah, Sabadi, Ṣebina, Jadau, ati Joeli, Benaiah.

44. Gbogbo awọn yi li o mu ajeji obinrin ba wọn gbe, omiran ninu wọn si ni obinrin nipa ẹniti nwọn li ọmọ.

Esr 10