Esr 10:33-40 Yorùbá Bibeli (YCE)

33. Ninu awọn ọmọ Haṣumu; Mattenai, Mattatta, Sabadi, Elifeleti, Jeremai, Manasse, ati Ṣimei.

34. Ninu awọn ọmọ Bani; Maadai, Amramu ati Ueli.

35. Benaiah, Bedeiah, Kellu,

36. Faniah, Meremoti, Eliaṣibu,

37. Mattaniah, Mattenai ati Jaasau,

38. Ati Bani, ati Binnui, Ṣimei.

39. Ati Ṣelemiah, ati Natani, ati Adaiah,

40. Maknadebai, Saṣai, Ṣarai,

Esr 10