Esr 1:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Kirusi ọba si ko ohun èlo ile OLUWA jade, ti Nebukadnessari ti ko jade lọ lati Jerusalemu, ti o si fi sinu ile ọlọrun rẹ̀;

Esr 1

Esr 1:1-8