Esek 44:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn kì yio si sunmọ ọdọ mi, lati ṣiṣẹ alufa fun mi, tabi lati sunmọ gbogbo ohun-mimọ́ mi, ni ibi mimọ́ julọ: nwọn o si rù itijú wọn, ati ohun-irira wọn ti nwọn ti ṣe.

Esek 44

Esek 44:8-21