Esek 44:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn awọn Lefi ti o ti lọ jina kuro lọdọ mi, ni ìṣina Israeli, ti nwọn ṣìna kuro lọdọ mi lẹhin oriṣa wọn: yio si rù aiṣedede wọn.

Esek 44

Esek 44:1-12