Esek 39:20 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bayi li a o fi ẹṣin ati ẹlẹṣin bọ́ nyin yo lori tabili mi, pẹlu awọn alagbara, ati gbogbo awọn ologun, ni Oluwa Ọlọrun wi.

Esek 39

Esek 39:13-29