Esek 30:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

Etiopia, ati Libia, ati Lidia, ati gbogbo awọn olùranlọ́wọ, ati Kubu, ati awọn enia ilẹ na ti o mulẹ yio ti ipa idà ṣubu pẹlu wọn.

Esek 30

Esek 30:1-10