Esek 3:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

Mo si gbọ́ ariwo iyẹ́ awọn ẹ̀da alãye, ti o kàn ara wọn, ati ariwo awọn kẹkẹ́ ti o wà pẹlu wọn, ati ariwo iró nla.

Esek 3

Esek 3:5-17