Esek 3:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Pẹlupẹlu o wi fun mi pe, Ọmọ enia, gba gbogbo ọ̀rọ ti emi o sọ fun ọ si ọkàn rẹ, si fi eti rẹ gbọ́ wọn.

Esek 3

Esek 3:1-14