Esek 28:19 Yorùbá Bibeli (YCE)

Gbogbo awọn ti o mọ̀ ọ lãrin awọn orilẹ-ède li ẹnu o yà si ọ: iwọ o jẹ ẹ̀ru, iwọ kì yio si si mọ́ lailai.

Esek 28

Esek 28:15-23