Esek 27:33 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati ọjà-tità rẹ ti okun jade wá, iwọ tẹ́ orilẹ-ède pupọ lọrun; iwọ fi ọ̀pọlọpọ ọrọ̀ rẹ, ati ọjà rẹ, sọ awọn ọba aiye di ọlọrọ̀.

Esek 27

Esek 27:24-35