Esek 26:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

Yio jẹ ibi ninà awọ̀n si lãrin okun: nitori mo ti sọ ọ, li Oluwa Ọlọrun wi: yio si di ikogun fun awọn orilẹ-ède.

Esek 26

Esek 26:1-13