Esek 25:15 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bayi li Oluwa Ọlọrun wi; Nitori ti awọn ara Filistia ti lò ilo ẹsan, ti nwọn si ti fi ọkàn ti o kún fun arankàn gbẹsan, lati pa a run, nitori irira atijọ.

Esek 25

Esek 25:6-17