Esek 22:27 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn ọmọ-alade ãrin rẹ̀ dabi kõkò ti nṣọdẹ, lati tàjẹ silẹ, lati pa ọkàn run, lati jère aiṣõtọ.

Esek 22

Esek 22:23-28