Esek 22:15 Yorùbá Bibeli (YCE)

Emi o fọ́n ọ ká sãrin awọn keferi, emi o si tú ọ ká si orilẹ-ède gbogbo, emi o si run ẽri rẹ kuro lara rẹ.

Esek 22

Esek 22:11-18