Esek 21:23 Yorùbá Bibeli (YCE)

Afọ̀ṣẹ na yio si dabi eké fun wọn, loju awọn ti o ti bura fun wọn: ṣugbọn on o mu aiṣedẽde wá si iranti, ki a ba le mu wọn.

Esek 21

Esek 21:14-26