Esek 20:22 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn mo fà ọwọ́ mi sẹhìn, mo si ṣiṣẹ nitori orukọ mi, ki o má bà di ibajẹ li oju awọn keferi, loju ẹniti mo mu wọn jade.

Esek 20

Esek 20:19-28