Esek 2:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati awọn, bi nwọn o gbọ́, tabi bi nwọn o kọ̀, (nitori ọlọtẹ̀ ile ni nwọn) sibẹ nwọn o mọ̀ pe woli kan ti wà larin wọn.

Esek 2

Esek 2:2-7