Esek 19:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana ni awọn orilẹ-ède kó tì i nihà gbogbo lati ìgberiko wá, nwọn si na awọ̀n wọn le e lori: a mu u ninu iho wọn.

Esek 19

Esek 19:1-13