Esek 19:1-3 Yorùbá Bibeli (YCE)

1. PẸLUPẸLU iwọ pohùn-rére ẹkun fun awọn ọmọ-alade Israeli,

2. Si wipe, Kini iyá rẹ? Abo kiniun: o dubulẹ lãrin kiniun, o bọ́ awọn ọmọ rẹ lãrin ọmọ kiniun.

3. O si tọ́ ọkan ninu ọmọ rẹ̀ dàgba: o di ọmọ kiniun, o si kọ́ ati ṣọdẹ; o pa enia jẹ.

Esek 19