Esek 18:26 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati olododo kan ba yipada kuro ninu ododo rẹ̀, ti o si huwà aiṣedẽde, ti o si kú ninu wọn; nitori aiṣedẽde rẹ̀ ti o ti ṣe ni yio kú.

Esek 18

Esek 18:25-27