Esek 13:1-3 Yorùbá Bibeli (YCE)

1. Ọ̀RỌ Oluwa si tọ̀ mi wá, wipe:

2. Ọmọ enia, sọtẹlẹ si awọn woli Israeli ti nsọtẹlẹ, ki o si wi fun awọn ti nti ọkàn ara wọn sọtẹlẹ pe, Ẹ gbọ́ ọ̀rọ Oluwa;

3. Bayi li Oluwa Ọlọrun wi, egbé ni fun awọn aṣiwere woli, ti nwọn ntẹ̀le ẹmi ara wọn, ti wọn kò si ri nkan!

Esek 13