Esek 12:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Wi fun wọn pe, Bayi li Oluwa Ọlọrun wi; Ẹrù yi hàn fun awọn ọmọ-alade ni Jerusalemu, ati gbogbo ile Israeli ti o wà lãrin wọn.

Esek 12

Esek 12:1-17