Eks 9:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

OLUWA si wi fun Mose ati fun Aaroni pe, Bù ikunwọ ẽru ninu ileru, ki Mose ki o kù u si oju-ọrun li oju Farao.

Eks 9

Eks 9:2-18